Argẹntínà
| Argentine Republic[1]
República Argentina
|
||||||
|---|---|---|---|---|---|---|
|
||||||
| Motto: En unión y libertad "In Unity and Freedom" |
||||||
| Orin-ìyìn orílẹ̀-èdè: Himno Nacional Argentino |
||||||
|
Orthographic projection of Argentina
|
||||||
| Olúìlú (àti ìlú títóbijùlọ) |
Buenos Aires 34°36′S 58°23′W / 34.6°S 58.383°W |
|||||
| Èdè oníbiṣẹ́ | Spanish | |||||
| Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | 86.4% European (mostly Italian and Spanish) 8% Mestizo 4% Arab and East Asian 1.6% Amerindian [2][3] |
|||||
| Orúkọ aráàlú | Ará Argẹntínà | |||||
| Ìjọba | Federal presidential republic | |||||
| - | President | Cristina Fernández de Kirchner | ||||
| - | Vice President | Julio Cobos | ||||
| - | Supreme Court President | Ricardo Lorenzetti | ||||
| Independence | from Spain | |||||
| - | May Revolution | 25 May 1810 | ||||
| - | Declared | 9 July 1816 | ||||
| Ààlà | ||||||
| - | Àpapọ̀ iye ààlà | 2,766,890 km2 (8th) 1,068,302 sq mi |
||||
| - | Omi (%) | 1.1 | ||||
| Alábùgbé | ||||||
| - | Ìdíye 2008 | 40,482,000 (33rd) | ||||
| - | 2001 census | 36,260,130 | ||||
| GIO (PPP) | ìdíye 2008 | |||||
| - | Iye lápapọ̀ | $572.668 billion[4] (23rd) | ||||
| - | Ti ẹnikọ̀ọ̀kan | $14,408[4] (57th) | ||||
| GIO (onípípè) | Ìdíye 2008 | |||||
| - | Àpapọ̀ iye | $324.767 billion[4] (31st) | ||||
| - | Ti ẹnikọ̀ọ̀kan | $8,171[4] (66th) | ||||
| Gini (2006) | 49[5] (high) | |||||
| HDI (2006) | ▲ 0.860 (high) (46th) | |||||
| Owóníná | Peso (ARS) |
|||||
| Àkókò ilẹ̀àmùrè | ART (UTC-3) | |||||
| - | Summer (DST) | ART (UTC-2) | ||||
| Ìwakọ̀ ní ọwọ́ | right (trains ride on the left) | |||||
| Àmìọ̀rọ̀ Internet | .ar | |||||
| Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù | +54 | |||||
Argentina Nínú ètò ìkànìyàn 1995, iye àwọn ènìyàn tí ó wà ní orílẹ̀-èdè Ajẹntínà (Argentiana) lé díẹ̀ ní mílíọ̀nù mẹ́rìnlélógójì àti àti ààbọ̀ (34, 513, 000). Èdè Pànyán-àn ni èdè tí wọ́n fi ń ṣe ìjọba ní ibẹ̀. Àwọn èdè mìíràn tí wọ́n tún ń sọ ní orílè-èdè yìí lé ní ogún. Lára àwọn ogún èdè yìí ni àwọn èdẹ̀ tí wọ́n ń pè ní Àmẹ́rídíánà (Ameridian Languages) wà. Ara àwọn èdè. Àmérídíánà yìí ni ‘Guarani, Araucanian, Metaco àti Quechua’. Àwọn èdè tí ó tún wà lára ogún yìí ni èdè tí àwọn tí ó wá se àtìpó ń sọ. Lára wọn ni èdè Ítílì (Ìtahàn) àti Jámánì (herman). Èdè Gẹ̀ẹ́sì ti ń gbilẹ̀ sí i ní orílẹ̀-èdè yìí gẹ́gẹ́ bí èdè fún òwò àgbáyé àti èdè àwọn tí ó ń ṣe àbẹ̀wò wá sí ibẹ̀ (International trade and tourism). Wọ́n ń lo èdè Gẹ̀ẹ́sì yìí pẹ̀lú èdè Pànyán-àn.
| Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- ↑ Article 35 of the "Constitution" (PDF). Archived from the original (PDF) on 2007-11-22. gives equal recognition to "United Provinces of the River Plate", "Argentine Republic" and "Argentine Confederation" and authorises the use of "Argentine Nation" in the making and enactment of laws
- ↑ Ben Cahoon. "Argentina". World Statesmen.org.
- ↑ "Encuesta Complementaria de Pueblos Indígenas 2004-2005". National Institute of Statistics and Census of Argentina. (Híspánì)
- ↑ 4.0 4.1 4.2 4.3 "Argentina". International Monetary Fund. Retrieved 2009-10-01.
- ↑ "Distribution of family income – Gini index". The World Factbook. CIA. Retrieved 2009-09-01.
| Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Argentina |
|
||||||||||||||