BBC News, Yorùbá - Ìròyìn
Ìròyìn tó ṣe kókó
Kojú ọ̀wọ́ngógó pẹ̀lú àwọn oúnjẹ aṣaralóòre yìí tí owó wọn kò wọ́n rárá
Bí ọ̀wọ́n gógó oúnjẹ ṣe ń lékún ní gbogbo ìgbà tí owó tó ń wọlé fún èèyàn kò sì lékún jẹ́ kí ó ṣòro láti máa rí àwọn oúnjẹ tó dára jẹ.
''Ìyàlẹ́nu ló jẹ́ pé èmi nìkan ni akẹ́kọ̀ọ́ tó dá wà ní kíláàsì láti 100l dé 400l''
Mojoyinoluwa, akẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀ ìṣìrò tó dá wà ní kíláàsì láti 100l dé 400l
Ẹlẹ́wọ̀n méjìlá sálọ, wọ́dà kan gbẹ́mìí mì ní Kogi
Ileeṣẹ ọgba ẹwọn ni Naijiria ti n wa awọn ẹlẹwọn mejila to sa kuro nipinlẹ Kogi
Orin, Kò ṣe é má gbọ̀ọ́, Duration 1,03
Àkójọpọ́ ìròyìn tí kò ṣeé má gbọ̀ọ́
Ojú dúdú, ẹsẹ̀ funfun - Ẹ wo nnkan tó mú ìyá ọlọ́mọ́ mẹ́fà bóra fún gbogbo ọmọ rẹ̀
Nibi tọrọ naa de duro bayii, Fatimo loun n kabaamọ igbesẹ ara bibo toun gbe naa, nitori aburu to ṣe lara awọn ọmọ oun.
Kí ló n fa ikọ́ọfe àti pé báwo lo ṣe le dènà rẹ̀?
Aarun ikọọfe jẹ ọkan gboogi ailera to maa n ṣakoba fun ẹdọforo lara awọn to ba lugbadi rẹ.
Ǹjẹ́ o mọ̀ pé gbígbọ́ ariwo lè fa ikú òjijì fún èèyàn?
Ariwo pipa, ijamba rẹ koda o ju ki eti di lasan lọ.
Àdó olóró ọmọ ogun Israeli pa olóri olóṣèlú Hamas ni Gaza
Ikọ ologun Isreali bẹrẹ ikede lati pa Hamas run latari ikọlu to ti waye lati ọjọ keje, oṣu Kẹwaa ọdun 2023.
Ọlọ́pàá bínú yínbọn mọ́ èèyàn mẹ́ta ní Cross River, ọ̀kan kú, méjì balẹ̀ sílè ìwòsàn
Ileeṣẹ ọlọpaa ti fi di isẹlẹ naa mulẹ ninu atẹjade kan ti wọn fi lede lọjọ Aiku, ọjọ Kẹtalelogun oṣu kẹta ọdun 2025.
Pope Francis farahàn fún ìgbà àkọ́kọ́ láti ilé ìwòsàn Rome
Lati bi ọsẹ mẹfa sẹyin ni Pope ti wa ni ile iwosan
'Àrùn tó lé ní 80 ni dókítà lè fi ìwọ́ àti olubi ọmọ wò'
Iwadii ijinlẹ awọn dokita oniṣegun oyinbo ti fidi ẹ mulẹ, pe ohun to yẹ ka tọju, ṣe lọjọ nilana ti ko fi ni i bajẹ ni olubi ọmọ jẹ.
Ọlọ́pàá bẹ̀rẹ̀ ìwádìí ikú ọkùnrin tí wọ́n gún pa níbi àdúrà Tahajjud
Agbẹnusọ ileesẹ ọlọpaa ipinlẹ Kaduna, Mansir Hassan, lo fi ọro naa lede ninu atẹjade kan.
BBC News Yorùbá ti wà lórí ìkànnì WhatsApp
Má jẹ́ kí etí rẹ ó di sí gbogbo ìròyìn ohun tó ń lọ ní Naijiria àti káàkiri àgbáyé. Mọ̀ nípa wọn lórí ìkànnì Whatsapp rẹ
Ìròyìn Àkàgbádùn
Fídíò, Ọmọ ọdún mẹ́ta rèé, tó ń ṣe irun lóge pẹ̀lú àrà oríṣiríṣi, Duration 1,18
Amina Yukubu, ìyá Nancy Lordina sọ fún BBC pé nítorí ọmọ òun ni ọ̀pọ̀ èèyàn ṣe máa ń wá ṣe irun ní ṣọ́ọ̀bù òun.
Orin, Kò ṣeé má gbọ̀ọ́, Duration 0,59
Kò ṣeé má gbọ̀ọ́
Naira Marley jẹri nílé ejọ̀ lórí ikú Mohbad
Naira Marley darapọ mọ igbẹjọ naa lati ori oju opo ayelujara lọjọ Ẹti, to si sọ fun ile ẹjọ nipa ohun sẹlẹ nipa iku Mohbad.
Alákòóso ní Rivers kìlọ́ fáwọn oníwàhálà bí PANDEF ṣe fọnmú mọ́ Tinubu lọ́wọ́ lórí ìkéde ìlú kò fararọ
Lẹ́yìn ìkéde ìlú kò fararọ ní Rivers, ẹgbẹ́ ọmọ bíbí agbègbè Niger Delta ní Tinubu fi igi gún ojú olóore, bí alákòóso tuntun ṣe ń kìlọ̀ fáwọn oníwàhálày.
Akọ̀ròyìn ní Ghana yóò gba $18m owó ìtanràn bó ṣe jàre ẹjọ́ ìbanilórúkọjẹ́ tó pé aṣòfin kan
Kootu to jokoo lorilẹede America lo paṣẹ, pe ki aṣofin naa san owo tiye rẹ jẹ $18m fun Anas gẹgẹ bii owo itanran fun ibanilorukọjẹ.
Àwọn ṣọ́jà Sudan gba ilé ìjọba padà lẹ́yìn ogun abẹ́lé ọlọ́dún méjì
Nabil Abdallah, agbẹnusọ awọn ṣọja ni Sudan, ṣalaye lẹka iroyin abẹnu wọn, pe awọn ṣọja ti fipa gba ile ijọba naa ati awọn ile mi-in to jẹ tijọba to wa ni aarin gbungbun Khartoum.
Èèyàn méji bọ́ sọ́wọ́ ọlọ́pàá n'Ibadan fún pé wọ́n ní ẹ̀yà ara èèyàn lọ́wọ́
Alukoro ọlọpaa ipinlẹ Oyo, Adewale Osifeso, ṣalaye ninu atẹjade to fi sita, pe awọn afurasi yii ko niṣẹ meji ju ki wọn maa hu oku eeyan ki wọn si maa ta a fun oogun owo lọ.
Abẹ̀ṣẹ́kú-bí-òjò, George Foreman, jáde láyé
Idile Foreman lo kede ipapoda naa loju ọpọ ayelujara Instagram
Nnamdi Kanu ní òun kò jẹ̀bi ẹ̀sun ìgbésùnmọ̀mí bí ìgbẹ́jọ́ rẹ̀ ṣe bẹ̀rẹ̀ lọ́tun níwájú adájọ́ tuntun
Tẹ o ba gbagbe, ijọba Naijiria lo fẹsun kan Kanu pe o fẹẹ da oju ijọba bolẹ, pẹlu idasilẹ ẹgbẹ 'Indigenous People of Biafra' (IPOB) to n ja fun.
Ìgbẹ́jọ́ Abdulrahman gbọ̀nà míì yọ, àṣírí tú nípa ibi tó wà, agbẹjọ́rò ìjọba àti tàwọn afurasí tako ara wọn
Awọn agbẹjọro ijọba ati tawọn afurasi tako ara wọn lori boya ki igbẹjọ tẹsiwaju bayii tabi ki wọn duro de ẹkunrẹrẹ iwadii lori isẹlẹ naa.
Fídíò, Àwọn ọ̀dọ́ méjì tó já bàálù gbà lọ́dún 1993 torí ìbò June 12 bá BBC sọ̀rọ̀, Duration 2,05
Akọroyin BBC, Mobolaji Olatunde bawọn ọdọ meji to ja baalu naa gba sọrọ, wọn si salaye ohun ti oju wọn ri lati ọdun mejilelọgbọn sẹyin, ti isẹlẹ naa ti waye.
Fídíò, "Kò rọrùn rárá láti gbaradì fún ìdíje ìrin oge Guiness World Record, N80m ló ná mi", Duration 3,12
BBC Yorùbá bá Ololade Ayelabola tó gba àmi ẹ̀yẹ Guinness World Records nínú ìdíje arìnrinoge, tó sì sọ̀rọ̀ nípa igbaradi rẹ fun idije naa, iye to na lati bo se bori nibi idije naa.
Ìròyìn Pàtàkì
Kọ́milẹ́kọ̀ọ́
Ẹ tẹ̀lé wa lórí ìkànnì ayélujára
Móríwú
Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn
Ipa wo ni ìpinnu Dangote láti má gba náírà fún epo rẹ̀ mọ́ yóò ní lára owó ilẹ̀ wa?
Tẹ o ba gbagbe, oṣu Kẹwaa ọdun 2024 ni ileeṣẹ Dangote tọwọ bọwe adehun pẹlu NNPCL lati maa ta epo pẹlu owo naira.
Wo ìgbà márùn-ún tí wọ́n ti kéde ìlú ò fararọ ní Nàìjíríà
BBC ṣàgbéyẹ̀wò àwọn ìgbà tí ìṣẹ̀lẹ̀ bẹ́ẹ̀ ti wáyé àti ohun tó ṣokùnfà wọn.
Ilé ẹjọ́ fún Oriyomi Hamzat àti olorì Naomi ní ọ̀nà àbáyọ láti tètè yanjú ìgbẹ́jọ́ wọn
Ti ẹ ko ba gbagbe ọmọde marundinlogoji lo ku nibi eto ti wọn gbe kalẹ lati ṣe iranwọ fun awọn to ku diẹ kaato fun lawujọ ni ipari ọdun 2024.
Irọ́ ni ìjọba Oyo pa lórí oyè Eleruwa, agbára atóbi má ṣeé báwí ni ó lò lé wa lórí - Ìdílé Laribikusi fapá jánú
Idile Laribikusi sọrọ tako alaye ti Kọmisana fun eto iroyin, Ọmọọba Dọtun Oyelade ṣe saaju asiko yii pe awọn lọra lati fa ọmọ oye kalẹ.
Bàbá onílé yìnbọn mọ́ ọmọdé tó gbá bọ́ọ̀lù sínú ọgbà ilé rẹ̀, ọ̀rọ̀ bẹ́yìn yọ
Bàbá náà ni wọ́n ló yìnbọn mọ́ Paul Victor, ẹni ọdún mẹ́rìndínlógún nítorí pé ọmọ náà wọ inú ọgbà ilé rẹ̀ láti lọ mú bọ́ọ̀lù rẹ̀ tó jábọ́ síbẹ̀.
Aráàlú yabo ọ́fíìsì gómìnà pẹ̀lú òkú èèyàn márùn-ún tí wọ́n ní afurasí darandaran pa l‘Ondo
Awọn olufehonuhan naa sọ pe iha ko kan mi, ati aibikita ni Gomina Lucky Aiyedatiwa n hu lori iṣẹlẹ ipaniyan ati ijinigbe to n waye lagbegbe Ala lati bii oṣu meji sẹyin.
Kóòtù fagilé ẹjọ́ Oriyomi àti Naomi, wọ́n kò lẹ́jọ́ jẹ́ mọ́
Agbẹnusọ ijọba Ipinlẹ Oyo lori ẹjọ naa, Abiodun Aikomo, sọ fun kootu pe gbogbo awọn obi ti iṣẹlẹ to pa ọmọ marundinlogoji n'Ibadan naa kan ni wọn ti san owo gba mabinu fun.






























































